Copertina del podcast

ÀRÒFỌ̀ AKÉWÌ

  • IPÒ EWÌ KÍKÉ LÁWÙJỌ LÉNÌÍ

    11 LUG 2020 · Ètò yí ni àkọ́kọ́ṣe lórí ìkànnì yí , ohun tí a gbé ètò yí kalẹ̀ fún ní láti máa ṣe ìgbélárugẹ̀ fún ewì alohùn Yorùbá àti kíkọ́ rẹ̀ pẹ̀lú. Ètò alẹ́ èní ń ṣe àfihàn ìgbéjáde ewì alohùn ÒGÚLÚǸTU láti ọwọ́ọ Ìgè Àdùbí. Ìgè Àdùbí Atọ́kùn ètò
    Ascoltato 14 min. 51 sec.

ÀRÒFỌ̀ AKÉWÌ jẹ́ ètò àtàtà èyí tó ń buyì kún Àṣà àti ìṣe ẹ̀yà Yorùbá nípa gbígbárùkù ti ìgbega fún ewì àti ọ̀rọ̀ àtẹnudẹ́nu ẹ̀yà Yorùbá. Ètò yíí yóò ma...

mostra di più
ÀRÒFỌ̀ AKÉWÌ jẹ́ ètò àtàtà èyí tó ń buyì kún Àṣà àti ìṣe ẹ̀yà Yorùbá nípa gbígbárùkù ti ìgbega fún ewì àti ọ̀rọ̀ àtẹnudẹ́nu ẹ̀yà Yorùbá. Ètò yíí yóò ma ṣe àfihàn àwọn Akéwí àti Olùkọ̀tàn Yorùbá nílẹ̀ yí àti lókè òkun. A yóò ma ka ìtàn ní àkàgbádùn, bẹ́ẹ̀ lọmọ ṣorí fún ewì lédè Yorùbá, tí a yóò sì ma fi eré orí-ìtàgé ní kíkà dára ya.
mostra meno
Informazioni
Autore AROKO ONLINE RADIO
Categorie Arte
Sito -
Email -

Sembra che non tu non abbia alcun episodio attivo

Sfoglia il catalogo di Spreaker per scoprire nuovi contenuti

Corrente

Copertina del podcast

Sembra che non ci sia nessun episodio nella tua coda

Sfoglia il catalogo di Spreaker per scoprire nuovi contenuti

Successivo

Copertina dell'episodio Copertina dell'episodio

Che silenzio che c’è...

È tempo di scoprire nuovi episodi!

Scopri
La tua Libreria
Cerca